Chapter 8 - Orí K jæ ARE YOU FEELING GOOD TODAY?

Similar documents
Àwæn örö (Vocabulary) Nouns

Iwifún nipa Ilé Ikójôpõ Iwé ti Ile Geesi

Sample Lesson on Saworoide (Kelani, 1999)

Reconstruction of Our Yoruba History - 5. Language has been described as ⠜(a) Communication of thoughts and feelings through a

PARALLELISM IN THE YORUBA NAMING CEREMONY EWÌ (POEM) BY ABIODUN ADEPOJU AFRICAN RESEARCH PRESENTATIONS NAME: FLORENCE OLAMIJULO

Awọn Obirin Ninu Islam

The Element of Symbolism in non-animals featured in the Yorùbá Healthrelated

Radio Advertisement and Yoruba Oral Genres Oluwatoyin Olaiya & Adekemi Taiwo Ekiti State University, Nigeria

The Use of Music in Equipping the Nigerian Child for Civic Challenges

A1 Personal (Subject) Pronouns

The Ethics of Work in the Music of Sholla Allyson Obaniyi. Lawrence O. Bamikole

Lesson 60: Visit to the Doctor / Dentist (20-25 minutes)

LESSON 26: DEPENDENT CLAUSES (ADVERB)

A Pragmatic Study of Yoruba Proverbs in English

.Student A ... Student B

ELEMENTARY GRAMMAR LABORATORY 1ST SEMESTER

Interpreting Yoruba proverbs: Some hearer strategies

SAMPLE LESSON FOR PRONOUNS

Lesson 35: Sick Day (20-25 minutes)

Contents. Section 1 VERBS...57

Parts of the Body: Level 3. Directions: Write about the picture and answer the questions. Read your story to your group when you are finished.

Get ready 1 Talk about the pictures

Joel Martinson (Choral score) Selah Publishing Co., Inc. Hn. J œ œ œ œ œ œ. j œ. 8 5 Choir: (Women or Men) for review only. ni- mi- pax.

Ire and Ibi: The Yorùbá Concepts of Good and Bad*

6 see 7 take 8 give 9 are. to the library. There (2) a lot of new books about famous people. I (3) my Science teacher at the library.

About You: How Music Affects Your Moods

1 Family and friends. 1 Play the game with a partner. Throw a dice. Say. How to play

COPYRIGHTED MATERIAL. About Reading Pathways

HOLIDAY ASSIGNMENT PRIMARY

Here we go again. The Simple Past tense, is a simple tense to describe actions occurred in the past or past experiences.

South Avenue Primary School. Name: New Document 1. Class: Date: 44 minutes. Time: 44 marks. Marks: Comments: Page 1

The rude man had extremely dirty finger nails. (1 mark) a) Circle the three words in the sentence above that should start with a capital letter.

CONTENTS AND FEATURES OF YORUBA INCANTATORY POETRY ABSTRACT

10 J. K. R ow ling Her Story G ames and Toy s of P ioneer C anada (1) G ames and Toy s of P ioneer C anada (2) 46-49

Macmillan Publishers S.A. Sample material TALL TALES. What are tall tales? I love my lasso. I can catch it with my lasso!

NELTAS - ECAT GRADE 3

Part 1: Writing. Fundamentals of Writing 2 Lesson 5. Sentence Structure: Complex Sentences

DAV Centenary Public School

short long short long short long

voiced mark Ç 49 È go to page 52

English Olympiad Level 3

Yorùbá Worldview and Context for Irony of Fate in Selected Tragic Plays

PRE-ADOLESCENTS BEGINNERS WEB SAMPLE 2018 NEW CONTENTS

TheSyntaxofYoru baṕroverbs. The Syntax of Yorùbá Proverbs. By Timothy Adeyemi Akanbi

2017 Tentative Roster

Simple present tense vs. present continuous tense

The Crab: Journal of Theatre and Media Arts (Number 8/June 2013, ) Yoruba Folksongs and its Aphorism: A Study of Selected Folksongs

English Language Lesson two Dr. S. Fiala

Liz Driscoll. Common mistakesat PET. and how to avoid them

My collection of some of the most useful phrases spoken in Sinhala

Compound Subjects The compound subject has two or more connected common nouns, proper nouns, or pronouns that one verb acts upon. The words and, or, o

Pronunciation of final -ed

ii) Are we writing in French?. iii) Is there a book under the chair? iv) Is the house in front of them?

About You: How Music Affects Your Moods

Sentences. A sentence is a group of words that tells a complete thought. A sentence always tells who or what

CONTEÚDO PARA A PROVA DE RECUPERAÇÃO FINAL: Unit 1: Can & can't, Adverbs of frequency, Question word: (How often?), Imperatives.

GRADE 9 FINAL REVISION

A. Quickly skim the two articles. Circle the answers.

SAMPLE. Grammar, punctuation and spelling. Paper 1: short answer questions. English tests KEY STAGE LEVELS. First name. Middle name.

QUARTER 3 GUM REVIEW: UNITS Did you download and save the Quarter 3 GUM review sent in kmail or on my English website?

S. 2 English Revision Exercises. Unit 1 Basic English Sentence Patterns

GRAMMAR CURRICULUM LEVEL I

ENGLIGH REVIEW. 1ºy 2ºESO Colegio "La Inmaculada" Am, is or are? Write the correct word in the gaps. Then make the sentences negative.

Sample unit. me to ask him visit my aunt. about work there for you?

2 Do you buy comics? 3 Do you eat strawberry ice-cream? 4 Do you tidy your bedroom? 5 Do you see your grandparents at the weekend?

Grammar Flash Cards 3rd Edition Update Cards UPDATE FILE CONTENTS PRINTING TIPS

Key stage 2. English grammar, punctuation and spelling. Paper 1: questions national curriculum tests. First name. Middle name.

Is The Gray Book Right For My Student?

Grammar Glossary. Active: Somebody saw you. We must find them. I have repaired it. Passive: You were seen. They must be found. It has been repaired.

Section A: Comprehension (30 marks) Scribes in Ancient Egypt

Prof. Jendry E. Barrios O.

Write down the date when you first study a unit or section in Oxford Word Skills Advanced, then write down the date when you study it again.

INTERMEDIATE PLUS UNIT 9 (B3)

Second Term Examination Syllabus for Class 4 Blue & Green

Second Grade ELA Third Nine-Week Study Guide

CUADERNILLO DE REPASO CUARTO GRADO

MIDTERM~STUDY GUIDE. A declarative sentence makes a statement. It ends with a period.

winter but it rained often during the summer

Commonly Misspelled Words

SAMPLE. Grammar, punctuation and spelling. Paper 1: short answer questions. English tests KEY STAGE LEVELS. First name. Middle name.

Basic English. Robert Taggart

Anglia ESOL International Examinations. Preliminary Level (A1) Paper CC115 W1 [5] W3 [10] W2 [10]

Contents. sample. Unit Page Enrichment. 1 Conditional Sentences (1): If will Noun Suffixes... 4 * 3 Infinitives (1): to-infinitive...

On the weekend UNIT. In this unit. 1 Listen and read.

THE TECHNIQUES OF STORY-TELLING PERFORMANCE IN EKITI NARRATIVE TRADITION, NIGERIA

Grammar study guide run Vs./ run Verb Noun

Nä Wä Kamali i Hawai i

Date: Grade 5- Term 2

Pearson. Classmates. Vocabulary. I know that! In this unit. I can talk about school.

Language Arts Study Guide Week 1, 8, 15, 22, 29

Independent Reading Management Kit. Grades 4 6

Song Texts, Theme and Roles of Vocal Music in Egungun Traditional Festival in Akesan, Awori land of Lagos State

Key Stage 2 example test paper

LESSON 30: REVIEW & QUIZ (DEPENDENT CLAUSES)

The fear of the Lord is the start of wisdom, and the knowledge of the Holy One gives a wise mind. Bill s day

LESSON 7: ADVERBS. In the last lesson, you learned about adjectives. Adjectives are a kind of modifier. They modify nouns and pronouns.

Skill-Builders. Grades 3-4. Grammar & Usage. Writer Kathleen Cribby. Editorial Director Susan A. Blair. Project Manager Erica L.

Vocabulary Look at the words written in boldface in the Dialogue Box. Guess their meanings by how they are used in the sentences.

African Musician as Journalist: A Study of Ayinde Barrister s Works

Curriculum Materials Used

Transcription:

Chapter 8 - Orí K jæ ARE YOU FEELING GOOD TODAY? OBJECTIVES: In this chapter you will learn: - How to use possessive forms of emphatic pronouns - About parts of the body - How to express what to do with different parts of the body - About the future tense - About health and sickness - About different types of sport 185

Orí K jæ (Chapter 8) Àwæn örö (Vocabulary) Àwæn örö (Vocabulary) Nouns aboyún àgbo aládàáni apá apòògùn àrùn babaláwo babañlá èjìká eré sísá ewé ëka së ë«ê jíjà gbajúmö ìdàgbàsókè i«ê i«ê ab ìlú irin ìsê itan Ìyá Àbíyè nôösì òlíñpíìkì oní«ègùn oní«ê ab ölàjú yæyínyæyín (dókítà eyín) pregnant lady concoction private arm pharmacist disease/illness the healers ancestor shoulder athletics leaf branch leg/foot boxing common progress work surgery city/town tool thigh midwife nurse Olympics doctor surgeon civilization dentist COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 186 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Àwæn örö (Vocabulary) Noun Phrases agbára omi àti ewé alábòójútó erée bôölù àf sëgbá/r firí àlô pípa bôölù àjùsáwön bôölù àfæwôgbá bôölù àf sëgbá dókítà àrùn æpælæ dókítà eyín dókítà ojú dókítà olùtôjú obìnrin dókítà æmædé egbò igi/ egbòogi eléwé æmæ eré ìdárayá Ìjàkadì tàbí k ilé ìta òògùn ilé ìbímæ ilé ìwòsàn ìjæba ilé ëkô gíga i«àjogúnba i«ê àrùn wíwò I«ê ì«ègùn ìtôjú aboyún ìtôjú aláìsàn ìtôjú æmædé ìwé à«ìtôjú aláìsàn ìwòsàn òyìnbó ohun búburú òkè ærùn olùrànlôwô r firí oní«ègùn ìbílë òyìnbó amúnisìn æmæ ìkókó öpölæpö önà pápá ì«eré the power of water and herbs soccer referee telling of folktales basketball handball soccer psychiatrist dentist optometrist gynecologist pediatrician medicine herb seller sport/ game wrestling pharmacy delivery room Government/General hospital institution of higher education inherited job the job of curing diseases medical practice pre-natal care care of the sick children s care authorization to take care of the sick western medicine evil above the neck assistant referee/line man traditional doctor colonial master an infant several ways playground COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 187 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Àwæn örö (Vocabulary) Verbs dìde fò fún gbóòórùn gbôrö jà j un jókòó juwô kàpö kàwèé köwèé lò pàtêwô rà rêrìnín rìn ríran ronú sáré sín sunkún wë Verb Phrases bá jà (serial verb) fi «e (serial verb) fojú sí fæ nu fun fèrè gba bôölù gba ìwé à«gba ìwúre gbá t níìsì to stand up to jump to give to smell to hear to fight to eat to sit down to wave hand to put together to read to write to use to clap to buy to laugh to walk to see to think to run to sneeze to cry to take a bath to be afflicted with; fight with make do to observe to brush teeth to play trumpet; to blow balloon to play soccer to get permission go to parents for prayers to play tennis COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 188 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Àwæn örö (Vocabulary) jê ohun tí is something that j oúnj àárö to eat breakfast jogún àìsàn wíwò to inherit the healing of diseases jogún i«ê inherit the profession jöô kúrò ojère please, leave me alone kò ní láti gbà do not have to obtain kun ojú to put on make-up láti fi «e to make láti fi wo ààrùn to cure disease/illness láti já ewé to pluck leaves láti gbëbí to deliver (baby) láti mæ irú àrùn to know what type of disease lo agbára to use power læ sí ilé-ìwé to go to school læ rí (serial verb) to go see máa ñ bæ Òrì«à Ælômæ to worship the children s deity máa ñ dá ifá to consult the oracle máa ñ gbo pö to combine/to mix mö wípé to know that mú wá (serial verb) to bring ní ìgbàgbô wípé to have the belief that nu ara to dry body pa ara to put on body lotion ran lôwô to help «e ìtôjú æmæ ìkókó to take care of the infant sæ wípé to say that t dùrù to play piano tô nõkan wò to taste something wà lára to be among wo t lifí«àn to watch TV wæ a«æ to put on clothes wæ bàtà to wear shoes ya irun to comb hair COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 189 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Àwæn örö (Vocabulary) Adjectives öpölæpö wönyí wôpö yàtö Adverbs sáábà tún Adverbial phrase tí mo bá jí Prepositional phrases bíi Ò«un àti Æya inú igbó kí ayé tó di ayé ölàjú kí wôn tó lè «e kí wôn tó gba láti fi «e ìtôjú láti kékeré láti òkè òkun láti láti æwô àwæn babañlá lôwô Ìjæba ní àárín ní ìgbàgbô wípé ní òwúrö/àárö nípa nítorí èyí ni nítòrí ìdí èyí yàtö sí eléyìí several these common different usually also when I wake up such as Ò«un and Æya inside the bush/forest before the world became civilized before they can do/make before they can be given/awarded for taking care of from childhood from abroad/ from overseas from from the ancestors from government in between/in the middle of believe that in the morning about it s because of this for this reason; because of this besides this COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 190 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Àwæn örö (Vocabulary) Other Expressions àwæn èyí tí ó wôpö the most common bojúbojú àti kùn mêran types of hide and seek games Ìlera ni oògùn ærö health is wealth ìtumæ èyí ni pé this implies/this means that o dé nìy n You have come again ó «e pàtàkì láti it is important to púpö nínú a lot of / many «e tán on completion/completed tí ó bá ñ bá ènìyàn jà that people are afflicted with COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 191 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô Kìíní (Lesson 1) Lesson 1 - Ëkô Kìíní: Possessive forms of emphatic pronouns Possessive Pronouns Singular Plural 1 st pers. tèmi mine (m/f) 1 st pers. tàwa ours (m/f) 2 nd pers. tìwæ yours (m/f) 2 nd pers. tëyin yours (m/f) 3 rd pers. tòhun his/hers (m/f) 3 rd pers. tàwæn theirs (m/f) Emphatic pronouns have possessive forms derived from being preceded by ti. A B èmi ti + èmi tèmi ìwæ ti + ìwæ tìwæ òun ti + òun tòun àwa ti + àwa tàwa ëyin ti + ëyin tëyin àwæn ti + àwæn tàwæn Ti + emphatic subject pronouns above contract to become tèmi, tìwæ, etc. Notice that in the column B, the low tone on the first vowel of the pronoun is retained. Using possessive pronouns in sentences: -Tìwæ ni a«æ náà -The cloth is yours -Ìbídùn sæ pé tòun ni ìwé náà - Ìbídùn said that the book is hers -Tiwa ni ajá y n -The dog is ours COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 192 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô Kìíní (Lesson 1) I«ê»í«e 1 Fi èyí tó bá y dí àwæn àlàfo wönyí. Use the correct possessive pronoun in the blank space provided. 1. ni ìwé y n. (mine) 2. A«æ wà ní orí ibùsùn. (yours pl.) 3. Àwæn æmæ wà ní ilé-ëkô gíga. (ours) 4. Ìdánwòo ñ bërë ní öla. (yours sg.) 5. Nígbà wo ni ñ bërë? (yours pl.) I«ê»í«e 2 Fi èyí tó bá y dí àwæn àlàfo wönyí. Use the correct possessive pronoun in the blank space provided. Bí àp r : Tèmi ni ìwé y n (mine) 1. ni ìwé y n (ours). 2. ni ìwé y n (his/hers). 3. ni ìwé y n (theirs). 4. ni ìwé y n (yours pl.). 5. ni ìwé y n (yours sg.). COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 193 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô Kejì (Lesson 2) Lesson 2 - Ëkô Kejì Parts of the body Parts of the body 1 - Front view etí ojú imú irunmú ẹnu eyín àgbọǹ àyà ọwọ ikùn itan orúkún ẹsẹ àwọn ọmọ ìka ẹsẹ COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 194 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô Kejì (Lesson 2) Parts of the body 2 - Back view orí irun ọrùn èjìká ẹỳìn ìgùnpá apá itan ìka ọwọ The interrogative kí ni followed by what to do with the parts of the body Kí ni a = Kí la what do we? n = l COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 195 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô Kejì (Lesson 2) I«ê»í«e 1 Dárúkæ àwæn ëyà ara tí à ñ lò láti «e àwæn nõkan wönyí: Mention parts of the body that we use to do the following: 1. Kí la fi ñ ronú? 2. Kí la fi ñ rìn? 3. Àwæn ëyà ara wo ni a/ la fi ñ gbá bôölù? 4. Kí la fi ñ t dùrù? 5. Kí ló wa ni òkè ærùn? 6. Kí la fi ñ sunkún? 7. Kí la fi ñ rêrìnín? 8. Kí la fi ñ gbá t níìsì? 9. Kí la fi ñ wo t lifí«àn? 10. Kí la fi ñ ríran? 11. Kí ló wa ni òkè orí? 12. Kí la fi ñ j un? 13. Kí ló wa ni àárínin èjìká àti æwô? 14. Kí ló wà ní àárínin itan àti së? 15. Kí la fi ñ köwèé? 16. Kí la fi ñ fun fèrè? 17. Kí la fi ñ gbôrö? 18. Kí la fi ñ gbóòórùn? 19. Kí la fi ñ fò? 20. Kí la fi ñ pàtêwô? 21. Kí la fi ñ jà? 22. Kí la fi ñ sín? 23. Kí la fi ñ tô nõkan wò? 24. Kí la fi ñ sáré? 25. Kí la fi ñ kàwé? COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 196 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô Kejì (Lesson 2) I«ê»í«e 2 Sæ ohun tí à ñ fi àwæn ëyà ara wönyí «e. State what we use these parts of the body for. Bí àp r : orókún: a fi ñ kúnlë 1. ojú: 2. nu: 3. etí: 4. æwô: 5. orí: 6. imú: 7. së: 8. eyín: 9. ahôn: 10. apá: COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 197 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K ta (Lesson 3) Ìwòsànan ayé àtijô Lesson 3 - Ëkô K ta: Ìlera àti àìsàn (Health and illness) Kí ayé tó di ayé ölàjú, ewé àti egbòogi jê ohun tí àwæn babañláa wa máa ñ lò láti fi wo àrùn. Àwæn oní«égùn máa ñ læ sí inú igbó láti já ewé. Ewé àti egbòogi ni wôn máa ñ gbo pö láti fi «e ìtôjú àwæn ènìyàn. Ó «e pàtàkì láti mö wípé àwæn oní«ègùn máa ñ lo agbára orí«irí«i láti mæ irú àrùn tí ó bá ñ bá ènìyàn jà. Nítorí ìdí èyí, àwæn babaláwo máa ñ dá ifá láti mæ irú àrùn ti ó ñ «e ènìyàn. I«ê ì«ègun jê i«àjogúnba. Púpö nínú àwæn oní«ègùn ni wôn ñ jogún i«ê náa láti æwô àwæn babañláa wæn. Àwæn Yorùbá ní ìgbàgbô wípé ohun búburú ni àrùn jê. Nítorí èyí ni wôn fi máa ñ sæ wípé: Ìlera ni oògùn ærö. Ìtumæ èyí ni wípé, ìlera «e pàtàkì fún i«ê àti ìdàgbàsókè ènìyàn àti ìlú. Orí«irí«i àrùn ni ó máa ñ bá àwæn ènìyàn jà. Àwæn èyí tí ó wôpö ni ibàa jëdöjëdö, ibàa pônjúpôntö àti bêë bêë læ. Orí«irí«i ìtôjú ni ó wà fún orí«irí«i ènìyàn. Ìtôjú æmædé yàtö sí ìtôjú aboyún. Ìyá Àbíyè ni orúkæ tí wôn máa ñ pe oní«ègùn aboyún. Púpö nínú àwæn Ìyá Àbíyè ni wôn máa ñ bæ Òrì«à Ælômæ bíi Ò«un àti Æya. Agbára omi àti ewé ni àwæn Ìyá Àbíyè máa ñ lò láti gbëbí fun àwæn aboyún. Àwæn eléwé æmæ ni àwæn obìnrin tí wôn ñ sáábà máa ñ «e ìtôjú æmæ ìkókó. Orí«irí«i àgbo ni àwæn eléwé æmæ máa ñ kàpö láti fi «e ìtöjú æmæ ìkókó. I«ê»í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Kí ni àwæn Yorùbá máa fi ñ «e ìtôjú aláìsàn kí ayé tó di ayé ölàjú? 2. Önà wo ni àwæn oní«ègún máa ñ gbà mæ irú àrùn tí ó bá ñ bá ènìyàn jà? 3. Kí ni ìgbàgbô àwæn Yorùbá nípa àrùn? 4. Irú àwæn ènìyàn wo ni ó máa ñ «e ìtôjú àwæn æmædé àti àwæn aboyún ni ayé àtijö? 5. Bí àrùn bá kæjá nõkan tí a kò lè lo egbòogi fún, kí ni ohun pàtàkì tí àwæn onì«ègùn máa ñ «e? 6. Báwo ni púpö nínúu àwæn oní«ègùn ní ayé àtijô «e máa ñ di oní«ègùn? 7. Kí ni ohun pàtàkì tí àwæn tí ó ñ «e ìtôjú àwæn aboyún àti æmædé máa ñ lò látí «e ìtæjúu wæn? 8.»e àlàyée gbólóhùn yìí, Ìlera ni oògùn ærö. 9. Dárúkæ àwæn àrùn tí ó wôpö láàárín àwæn æmædé. 10. Àwæn wo ni wôn màa ñ tôjú aláìsàn ní ayé àtijô? COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 198 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 2 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following sentences. 1. Ní ayé àtijô, ni àwæn ènìyàn máa ñ lò fún ìwòsàn. a. ewé b. egbò c. ewé àti egbò igi d. ògùn òyìnbó 2. Àwæn ni wôn máa ñ «e ì«ègùn fún àwæn ènìyàn láyé àtijô. a. oní«ègùn òyìnbó b. oní«ègùn ìbílë c. oní«ègùn àgbáyé d. Babaláwo 3. Àwæn oní«ègùn láyé àtijô máa ñ kô i«ê ì«ègùn lôwô àwæn. a. oní«ègùn òyìnbó b. oní«ègùn funfun c. Babañláa wæn d. örê 4. Ìlera «e ní àwùjæ Yorùbá. a. wúlò b. pàtàkì c. oní«ègùn d. ìdàgbàsókè 5. ni ó ñ gbëbí fún àwæn aláboyún. a. Ìyá Àbíyè b. Babaláwo c. oní«ègùn òyìnbó d. eléwé æmæ COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 199 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K ta (Lesson 3) Ìwòsànan ti òde-òní Àwæn òyìnbó amúnisìn ni wôn mú èto ìwòsàn ìgbàlódé wá sí ilë Yorùbá. Ilé ìwòsàn ìgbàlódé ni àwæn dókítà àti onímö ì«ègùn ti máa ñ «e ìtôjú aláìsàn. Láti òkè òkun ni wæn ti máa ñ kó awæn irin ìsê ti wôn ñ lò wá. Ìwòsàn òyìnbó yàtö sí ti àwæn babañlá àwæn Yorùbá ní öpölæpö önà. Àwæn dókítà tàbí onímö ì«ègùn ní láti læ sí ilé-ëkô gíga láti kô i«ê ì«ègùn kí wôn tó lè «e ìtôjú aláìsàn. Öpölæpö ædún ni wôn sì máa ñ lò kí wôn tó gba ìwé à«láti lè tôjú aláìsàn. Púpö nínúu wæn ni wôn máa ñ fojú sí i«ê òbíi wæn láti kékeré. Orí«irí«i onímö ì«ègùn òyìnbó ni ó wà. Àwæn apòògùn ni wôn mö nípa pípo oògùn àti bí awæn ènìyàn «e lè ra oògùn. Àwæn apòògùn náa máa ñ læ sí ilé-ëkô gíga láti kô i«ê ì«ègùn òyìnbó. Yàtö sí eléyìí, àwæn nôösì ni àwæn obìnrin tàbí okùnrin tí ó máa ñ ran dókítà lôwô pëlú ìtôjú aláìsàn. Orí«irí«i dókítà ni ó wà. Díë nínúu wæn ni dókítà eléyin, oní«ê ab, dókítà æmædé, dókítà àrùn æpælæ, dókítà obìnrin tàbí aboyún, àti dókítà ojú. Ní ilé ìwòsàn òyìnbó, orí«irí«i ëka ni ó wà. Àwæn ilé ìwòsàn tí ó tóbi máa ñ ní ëka bíi i«ê ab, ilé ìta òògùn àti ilé ìbímæ. Àwæn ilé ìwòsàn ìjæba yàtö sí ti aládàáni. Dókítà aládàáni ní láti gba ìwé à«lôwô ìjæba kí ó tó lè «e i«ê àrùn wíwò.»ùgbôn àwæn oní«ègùn ìbílë kò ní láti gba ìwé à«kí wôn tó lè wo àìsàn. I«ê»í«e 3 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Sæ fún wa ìyàtö tí ó wà láàárín ìwòsàn ní ayé àtijô àti ti ayé òde-òní. 2. Àwæn wo ni ó mú ìwòsàn ìgbàlódé wá sí ilë Yorùbá? 3. Kí ni ìyàtö tí ó wà láàárín oní«ègùn ìbílë àti ti òyìnbó? 4. Báwo ni ènìyàn «e lè di oní«ègùn òyìnbó? 5. Õjê ìyàtö wà láàárín ìmö ì«ègùn òyìnbó àti ti ìbílë? Dárúkæ orí«i onímö ì«ègùn tí ó wá ní ayé òde òní. 6. Kí ni àõfààní ìmö ì«ègùn òyìnbó ní òde-òní? 7. Dárúkæ ìrú àwæn dókítà tí ó wá nípa ìmö ì«ègùn òyìnbó? 8. Níbo ni àwæn irin i«ê fún ìwòsàn òyìnbò ti máa ñ wá? 9. Kí ni àõfààní tí ilé ìwòsàn òyìnbó tí ó bá tóbí ní? 10. Kí ni ìyàtö tí ó wà láàárín ilé ìwòsàn ìjæba àti tí aládàáni? COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 200 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 4 Mú èyí tó y nínú àwæn wönyí sí ibi tó bá y. Check the appropriate category for the following expressions. Àwæn örö Ìwòsànan ti ayé átijô Ìwòsànan ti òde òní 1. àgbo 2. apòògùn 3. babaláwo 4. dókítà àrùn æpælæ 5. dókítà obìnrin tàbí aboyún 6. dókítà ojú 7. dókítà æmædé 8. dókítà eyín 9. egbò igi/ egbòogi 10. eléwé æmæ 11. ewé 12. Ìyá Àbíyè 13. nôösì 14. oní«ègùn aboyún 15. oní«ê ab COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 201 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K ta (Lesson 3) Ìsöröngbèsì (Dialogue) Jídé àti Túndé õ sörö nípa ìlera. Jídé: Túndé: Jídé: Túndé: Jídé: Túndé: Jídé: Túndé: Jídé: Túndé: Jídé: Túndé: Jídé: Túndé: Jídé: Túndé: Túndé, «é wàá wá sí ilé-ìwé lôla? Rárá o, nítorí pé araà mi kò yá. Orí ñ fô mi. Gbogbo ara ñ ro mí.»é o ní ibà ni? Ó dàbêë, «ùgbôn n kò mö.»ébí tí o bá ní ibà, wà á kàn læ rí dókítà ní ilé-ìwòsàn ìjæba ni. Õjê o mö wípé n kò fêràn láti máa læ sí ilé-ìwòsàn? Mo bërù abêrê púpö. Túndé, kì í «e gbogbo àìsàn ni ènìyàn ñ gba abêrê sí. Tí ó bá jê wípé ibà lásán ni, o lè mu àgbo. Háà, èèmi, àgbo kë! Ki ní y n korò bíi ewúro.»ebí kí àwæn òyìnbó tó dé, àgbo ni àwæn Yorùbá máa ñ mu. Àwæn Yorùbá «ì ñ mu àgbo títí dì ìsinyìí, «ùgbôn èmi kô. Mà á kúkú læ gba abêrê y n ni! Tí ojú, etí àti së bá ñ dùn ô ñ kô? Fún ojú, màá læ rí dókítà ojú ni.»ebí dókítà kò níí fún mi ní abêrê nínú ojú! Túndé, o kì í «e dókítà. Bêë ni, n kì í «e dókítà. Õjê o mö pé eyín ñ dun èmi náà? Háà! Wà á læ rí yæyínyæyín (dókítà eyín) nìy n. Wôn á fún ní abêrê nínú eyín. Jö ô kúrò o jère. O dé nìy n. COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 202 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 5 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Kí ni àrùn tí ó ñ «e Túndé? 2. Kí ni àrùn tí ó ñ «e Jídé? 3. Tí o bá ñ «e àìsàn, kí ni o máa «e? 4. Kí ló dé tí Túndé fi sæ wí pé jö ô kúrò o jère? 5.»é àwæn Yorùbá kò mu àgbo mô? I«ê»í«e 6 Wá àwæn örö wönyí Look for these words in the puzzle below. Pay attention to the tones! aboyún àgbo àrùn dókítà èjìká ewé nôösì oní«ègùn i«ê ìlú a i l u a g b o e w e à b u o b b a b r o n o o s i d e u n o g o e u f d ó k í t à e j i y d u y n o è m n l u j w I s ú b à d ú n j j s l i k e k è à g b o k n Ì h i u n r i n g r u a I s ê k ê n k ú n k ú u ù k t d o k à s w n à g ú k n n a m e g n e j a b o y i n i ô k n o w n Í g é n ô ö s ì «o i g o d é a «ê o w o e j ê s s i ê s h à b è d é ì é w a i e d a b ó y u n g à r l s n ó g ó g ó i à d à n ù m k ú à n o o ê s à g b e j à n ê n ö COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 203 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 7 Kæ ìtumö àwæn örö wönyí sílë ní èdèe Yorùbá. Write the meanings of these words in Yorùbá. 1. aboyún 2. àgbo 3. àrùn 4. dókítà 5. èjìkà 6. ewé 7. nôösì 8. oní«ègùn 9. i«ê 10. ìlú COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 204 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K rin (Lesson 4) Eré Ìdárayá àtijæ Lesson 4 - Ëkô K rin: Eré Ìdárayá (Sports) Orí«i eré ìdárayá méjì ni ó wà: ti ìta gbangba àti ti abêlé (abê ilé). Méjèèjì ni àwæn Yorùbá máa ñ «e láyé àtijæ títí di òní. Eré ìdárayá abêlé tí ó gbajúmö jù láàrín àwæn Yorùbá ni ayó títa. Tæmædé tàgbà, tækùnrin tobìnrin ní ó máa ñ ta á. Orí«irí«i erémædée Yorùbá tí ó j ti ìta gbangba ni erée bojúbojú àti kùn mêran. Ìjàkadì tàbí k ni eré ìta gbangba tí àwæn æmædé àti ödô tí wôn lágbára máa ñ «e látayé báyé. A kò gbödô gbàgbé àlô pípa gêgê bí orí«i eré«ùpá (ere ò«ùpá) kan. Ìy n ni pé lákòókò tí ò«ùpá bá môlë roko«o ni wôn máa ñ «e eré náà. Ní ìrú àkókò bêë, àgbàlagbà kan ni í máa kó àwæn æmædé jæ láti sötàn fún wæn. Orin, ijó, àti ìlù lílù pëlú àtêwô pípa ibë a máa mú kí àwæn æmædé gbádùnun rë, a sì máa dá wæn lára ya dáradára. I«ê»í«e 1 Dáhùn lóòótô ni tàbí lóòótô kô fún àwæn ìbéèrè wönyí. Answer Yes or No to the following questions. Òótô ni Òótô kô 1. Orí«i eré ìdárayá mêrin ni ó wà ní ayé àtijô. 2. Eré òde-òní ni ayò títa. 3. Àwæn àgbàlagbà nìkan ni wôn máa ñ ta ayò. 4. Ösán ni wôn máa n pa àlô. 5. Æmæ kékeré ni ó máa ñ pa àlô fún àwæn gbê rë. COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 205 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K rin (Lesson 4) I«ê»í«e 2 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following sentences. 1. Orí«i eré ìdárayá mélòó ni ó wá? a. mêta b. mêrin c. méjì d. márùnún 2. Eré ìdárayá abêlé tí ó gbajúmö jù láàárín àwæn Yorùbá ni? a. gbígba bôölù b. ayó títa c. wíwo t lifí«àn d. òkìtì títa 3. Eré ìdárayá àgbàlagba ni? a. ìjàkadì b. kùn mêran c. erée bojúbojú d. ayó títa 4. Eré ò«ùpá fún æmædé ni? a. kùn mêran b. àlô pípa c. ìjàkadì d. erée bojúbojú 5. Ta ni ó lè ta ayò? a. æmædé b. ækùnrin c. obìnrin d. gbogbo ènìyàn COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 206 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K rin (Lesson 4) Eré Ìdárayá òde-òní Lóde-òní tí ölàjú ti gbòde, eré ìdárayá ab lé bíi lúdò àti káàdì gbajúmö púpöpúpö. Orí«irí«i sì ni eré ìdárayá ìta gbangba lóde-òní. Lára wæn ni igi fífò, eré sísá, bôölù àjùsáwön, bôölù àfæwôgbá, ë«ê jíjà àti bôölù àf sëgbá. Bôölù àf sëgbá ní ó gbajúmö jùlæ nínúu gbogbo àwæn eré òde-òní ní orílë-èdè Nàìjíríà. Agbábôölù môkànlá ni ó máa wà ní æwô gbê agbábôölù kan ní oríi pápá lákòókò ìdíje. gbê agbábôölù méjì ni ó sì máa ñ díje ní akókò ì«eré. Nítorí náà agbábôölù méjìlélógún ni àpapö gbogbo agbábôölù tí wôn gbôdö wà lóríi pápá lákòókò ìdíje. R firí ni nì k tàlélógún. Òun sì ni alábòójútó erée bôölù àf sëgbá lóríi pápá. Ó sì máa ñ ní olùránlôwô méjì tí wôn máa ñ dúró sí ëgbëê pápá ì«eré. A lè pè wôn ní olùrànlôwôæ r firí. Lárá àwæn gbê agbábôölù tí ó lórúkæ ní orílë-èdè Nàìjíríà ni: Shooting Stars ti Ìbàdàn, Rangers International, Enyìmba Football Club ti Aba, Kano Pillars, Abiæla Babes àti bêë bêë læ. Super Eagles ni gbê agbábôölù tí ó ñ «ojú orílë-èdè Nàìjíríà. Lára àwæn agbábôölù tí wôn ti «e gudugudu méje àti yààyà mêfà lóríi pápá tí wôn sì lórúkæ gidi ni Túndé Balógun,»êgun Ædêgbàmí, Rà«ídì Yëkínnì, Peter Rùfáí, Kanu Nwankwo, Babangida Babayaro, Sunday Oliseh, Taribo West, Daniel Amokachi, Victor Ikpeba Augustin Jay-jay Okocha àti bêë bêë læ. Awæn gbê agbábôölù Super Eagles kò kërë rárá. Káàkiri àgbáyé ni wôn ti mö wôn bí ni mowó. Àwæn ni wôn gba Ife ëy ti àwæn orílë-èdè Adúláwö ní ædúnun 1994 àti ìdíje ti Olíñpíìkì ní ædúnun 1996. I«ê»í«e 3 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions. 1. Dárúkæ eré ìdárayá m rin tí ó mö ní òde-òní. 2. Sæ ìyàtö tó wà láàárìnin bôölù àjùsáwön àti bôölù àfæwôgbá. 3. Ènìyàn mélòó ni wôn máa ñ wà lóríi pápá ì«eré fún bôölù àf sëgbá? 4.»é gbogbo ènìyàn ni wôn mæ gbê agbábôölùu Super Eagles? 5.»é gbê agbábôölùu Super Eagles ni ó gba ife ëy àgbáyé ni ædúnun 1998? COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 207 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K rin (Lesson 4) I«ê»í«e 4 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following sentences. 1. Eré ìdárayá ab lé òde-òní ni? a. ayò b. lúdò c. eré sísá d. igi fífò 2. Orí«i eré ìdárayá ìta gbangba mélòó ni ó wá ni òde-òní nínú nõkan tí a kà? a. márùnún b. mêfà c. méje d. mêrin 3. Eré ìdárayá òde-òní wo ló gbajúmö jùlæ ní orílë-èdè Nàìjíríà? a. bôölù àfæwôgbá b. bôölù àjùsáwön c. ë«ê jíjà d. bôölù àf sëgbá 4. Ènìyàn mélòó ni ó wá ní gbê agbábôölù kan? a. méjìlélógún b. m tàlélógún c. môkànlá d. méjìlá 5. Olùránlôwô mélòó ni r firí máa ñ ní nínú bôölù àf sëgbá? a. mêrin b. mêta c. méjì d. márùnún COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 208 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K rin (Lesson 4) I«ê»í«e 5 Mú èyí tó y nínú àwæn wönyí sí ibi tó bá y. Check the appropriate category for the following expressions. Àwæn örö Eré Ìdárayá àtijæ Eré Ìdárayá òde-òní 1. alábòójútó erée bôölù 2. àf sëgbá/r firí 3. àlô pípa 4. bôölù àjùsáwön 5. bôölù àfæwôgbá 6. bôölù àf sëgbá I«ê»í«e 6 Kæ ìtumö àwæn örö wönyí sílë ní èdèe Yorùbá. Write down the meanings of these words in Yorùbá. 1. alábòójútó eré bôölù àf sëgbá 2. bojúbojú 3. Ìjàkadì tàbí k 4. ìwë wíwë 5. pápá ì«eré COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 209 CC 2011 The University of Texas at Austin

Orí K jæ (Chapter 8) Ëkô K rin (Lesson 4) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 210 CC 2011 The University of Texas at Austin