Àwæn örö (Vocabulary) Nouns

Similar documents
Chapter 8 - Orí K jæ ARE YOU FEELING GOOD TODAY?

Iwifún nipa Ilé Ikójôpõ Iwé ti Ile Geesi

Sample Lesson on Saworoide (Kelani, 1999)

Reconstruction of Our Yoruba History - 5. Language has been described as ⠜(a) Communication of thoughts and feelings through a

Awọn Obirin Ninu Islam

The Use of Music in Equipping the Nigerian Child for Civic Challenges

PARALLELISM IN THE YORUBA NAMING CEREMONY EWÌ (POEM) BY ABIODUN ADEPOJU AFRICAN RESEARCH PRESENTATIONS NAME: FLORENCE OLAMIJULO

New Words of Lesson 1. di4 yi1 ke4 sheng1 ci2

Tell me more about yourself

English as a Second Language Podcast ESL Podcast 169 Describing People s Appearance

HOLIDAY ASSIGNMENT PRIMARY

A Pragmatic Study of Yoruba Proverbs in English

Radio Advertisement and Yoruba Oral Genres Oluwatoyin Olaiya & Adekemi Taiwo Ekiti State University, Nigeria

voiced mark Ç 49 È go to page 52

Ask about any topics above which you can t understand, briefly speaking about each one when you have understood what it means.

The Ethics of Work in the Music of Sholla Allyson Obaniyi. Lawrence O. Bamikole

ELEMENTARY GRAMMAR LABORATORY 1ST SEMESTER

winter but it rained often during the summer

Activity 1: Warm-up Work in pairs. Look at these photos and discuss where, why and how people are taking selfies. Share your ideas with the group.

short ă /æ/ A bad can damage glass had happen happy have

Song Lessons Understanding and Using English Grammar, 3rd Edition. A lesson about adjective, adverb, and noun clauses (Chapters 12, 13, 17)

How do you say mesa in English? What is the meaning of board in Spanish? Can you repeat that, please? How do you spell country? May I come in?

1 Family matters. Vocabulary. Ages and stages of life. The family

Contents. Section 1 VERBS...57

LESSON 30: REVIEW & QUIZ (DEPENDENT CLAUSES)

The Element of Symbolism in non-animals featured in the Yorùbá Healthrelated

Pronouns and possessive adjectives


UNIT 1. The Individual and Society. Personal Identification. 4. Complete the instructions with a verb. 1. Write the missing letters.

Summer Term 2017 Year 5 French Prep

COPYRIGHTED MATERIAL. About Reading Pathways

Aretha Franklin, musical and political influencer, dies at 76

1 Look at the pictures and read about three families from around the world. Underline the family words.

Interpreting Yoruba proverbs: Some hearer strategies

Basic English. Robert Taggart

6 th Grade ELA Post-Test Study Guide Semester One

Lesson 35: Sick Day (20-25 minutes)

63 In QetQ example, heart is classified as noun: singular, common, abstract Homophones: sea/sea 68 Homophones: sea/see

Ire and Ibi: The Yorùbá Concepts of Good and Bad*

Units 1 & 2 Pre-exam Practice

CONTENTS AND FEATURES OF YORUBA INCANTATORY POETRY ABSTRACT

ENGLISH FILE Elementary

A new neighborhood. Lesson. Learning Objectives : After studying this lesson, you should be able to

Adverbs and Adjectives SPEAKING

UNIT 1: My Family and neighbor.

MIDTERM~STUDY GUIDE. A declarative sentence makes a statement. It ends with a period.

LEARNING GRAMMAR WORKBOOK 6 is specially designed to assess and expand the student s usage of grammar in the English Language.

Your English Podcasts. Vocabulary and Fluency Building Exercises. Pack 1-5. Scripts - Version for Mobile Devices (free)

Subjects & Predicates. Project LA Activity

Shurley Grammar Level 6 Chapter 8 Answer Key

Beloved musical icon Aretha Franklin dies at 76

Independent Reading Management Kit. Grades 4 6

LESSON 26: DEPENDENT CLAUSES (ADVERB)

6 th Grade ELA Post-Test Study Guide Semester One

ADVERBS MODIFYING VERBS

LESSON 7: ADVERBS. In the last lesson, you learned about adjectives. Adjectives are a kind of modifier. They modify nouns and pronouns.

2 nd Semester 2018 ENGLISH Grade: 3

UNIT 13: STORYTIME (4 Periods)

Person 2 person GRAMMAR AND READING. I m from Barcelona. and

UNIT. Talking about likes and dislikes. What you will learn in this unit:

On the Common Goods. Dr. Gregory Froelich

Yorùbá Worldview and Context for Irony of Fate in Selected Tragic Plays

Part 1: Writing. Fundamentals of Writing 2 Lesson 5. Sentence Structure: Complex Sentences

English 9 Final Exam Study Guide

The Crab: Journal of Theatre and Media Arts (Number 8/June 2013, ) Yoruba Folksongs and its Aphorism: A Study of Selected Folksongs

Sophomore Grammar points. 1. Hangman is a word game that both children and adults play.

Vowel contraction and deletion with personal prefixes

Role play Describing people. Relating the end of a story. Describing a sport. Describing a place. Expressing preference Making a decision

RETHINKING SCHOOLS PROOFREADING AND STYLE SHEET (November 2002)

Uppercase K. Counting to 30. Day 16

10 J. K. R ow ling Her Story G ames and Toy s of P ioneer C anada (1) G ames and Toy s of P ioneer C anada (2) 46-49

S. 2 English Revision Exercises. Unit 1 Basic English Sentence Patterns

International Journal of Literature, Language and Linguistics Vol. 1(1), pp , September, ISSN: XXXX-XXXX

List 5 words and their antonyms.

BRAIN INTERNATIONAL SCHOOL. Term II CLASS: IV ENGLISH REVISION SHEET

African Musician as Journalist: A Study of Ayinde Barrister s Works

Descriptive adjectives: - ed vs -ing. LEVEL NUMBER LANGUAGE Intermediate B1_2055G_EN English

Grammar Flash Cards 3rd Edition Update Cards UPDATE FILE CONTENTS PRINTING TIPS

Joel Martinson (Choral score) Selah Publishing Co., Inc. Hn. J œ œ œ œ œ œ. j œ. 8 5 Choir: (Women or Men) for review only. ni- mi- pax.

ENGLISH LANGUAGE TEST GRADE NINE

Key Stage 2 example test paper

Reference: Book: American Channel - Level: Beginners Unit: 1 Lesson 1 COURSE 1 PART A. Conversation Models and Patterns:

Fifth Grade Music History Video 2

Journey To The Centre of The Earth

Syntax: Sentence Structure

Ask Manu Italiano [Ep.008] How to make sentences in Italian

Unit 6. of Anna s family members in the correct spaces in the family tree. Look at the box with

Lesson 11. compound subject. 1. compound sentence words put together to make a new word. sentences joined to make a longer one

Course outline 30 weeks

Unit 1 People FEATURES. 1 Look at the photo and the caption. Where is the explorer? What is the photographer s name? 10 Explorers

A Super Fun French Project. Ma famille...et moi! Family-themed vocab. avoir+age etre adjective agreement sentence structure

Negative sentence structures

AP SPANISH LANGUAGE 2008 SCORING GUIDELINES (Form B)

Lesson 37: Quitting/Leaving (20-25 minutes)

Present perfect and simple past. LEVEL NUMBER LANGUAGE Beginner A2_2043G_EN English

第一课老师和学生. Teacher and Students

Key stage 2 - English grammar, punctuation and spelling practice paper

Punctuation Parts 1 & 2 E N G L I S H 2 1 M S. B R O W N

Language Arts Study Guide Week 1, 8, 15, 22, 29

Multifaces of Word in Yorùbá Orature

Transcription:

Chapter 5 - Orí Karùnún MY FAMILY TREE OBJECTIVES: In this chapter you will learn: - How to describe people by using the verbs jê, ni - How to use the negation kô - How to use the interrogative ta ni - How to describe one s family 111

Orí Karùnún (Chapter 5) Àwæn örö (Vocabulary) Àwæn örö (Vocabulary) Nouns aáwö àbúrò àgbà agbolé àdúgbò àgbàlagbà agb jôrò àkójæpö akêköô àlàáfíà apòògùn àpônlé ara à«à baálé burêwà dókítà ëgbôn ëkô ëwà gbogbo ìdàgbàsókè ìdöbálë ìdílé ìlú ìgbàgbô igun ìpàdé ì«ègùn ìtumö kódà differences younger sibling older person compound neighborhood older person lawyer collection student peace pharmacist respect body culture male head (of family) ugly doctor older sibling studies beans all progress, development prostration family (immediate) town, city, country belief branch (of family) meeting medicine the meaning in fact COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 112 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Àwæn örö (Vocabulary) mölêbí ojoojúmô ækæ olórí o«oo«ù ösöösë oúnj æjà æmædé pàjáwìrì píparí wúrà Noun Phrases bùrödáa lágbájá ètò bí family (extended) every month husband head every month every week food market youth emergency settling of; completion of gold brother (of somebody) organization of family Verbs dàrú confused, disorganized fún for gbé to live in/at gbædö must j to eat jê to be kúnlë kneel down parí to complete sörö to talk tí if túmö sí translates to/means/implies wí pé said that Verb Phrases bí tëlé kóra jæ lè dàrú to be born following to get together can lead to chaos; can be disorganized COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 113 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Àwæn örö (Vocabulary) kò ì tí ì has/have not yet máa ñ wáyé always takes place lágbára to be strong «e kókó is important; is crucial «e pàtàkì is important Adjectives ga kéré kúrú köökan sanra tóbi tínínrín Adverbs péré tall small short each fat big skinny (thin) only Conjunction àti nítorí èyí nítorí pé nípa and because of this because about Prepositional phrases láàárín nígbà mìíràn among, in the middle of at other times Interrogative mélòó ni Other Expressions ni tí ó bá juni læ ìdí èyí ni wí pé kí ayé ó gún ægbôn àti òye ökan lára how many? anyone that is older than oneself this/that is why for the world to be in good shape wisdom and understanding one of COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 114 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kìíní (Lesson 1) Lesson 1 - Ëkô Kìíní: The verbs jê to be and ni to be The Verb Jê The verb jê implies to be. It is frequently used with professions. For example: Ladi jê dókítà. Fadérera jê agb jôrò. Mo jê akêköô. Ladi is a doctor. Fadérera is an attorney/a lawyer. I am a student. The verb jê can be used to link phrases. For example: Ëwà jê oúnj tí ó dára láti j Beans are good to eat. Jê can also be used to express one s age. For example: Kêmi jê æmæ ædún mêwàá Màmáà mi jê æmæ ogójì ædún Kêmi is 10 years old My mother is 40 years old Jê + negation Jê kì í «e Ladi jê dókítà Ladi kì í «e dókítà Ladi is a doctor Ladi is not a doctor Mo jê akêköô N kì í «e akêköô I am a student I am not a student Kêmi jê æmæ ædún mêwàá Kêmi kì í «e æmæ ædún mêwàá Kêmi is 10 years old Kêmi is not 10 years old COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 115 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kìíní (Lesson 1) The verb Ni In Yorùbá, ni is another form of the verb to be as used in the sentences below: Èmi ni màmáa Túndé. Dókítà ni Ládi. Öla ni æjà Ìyá ni wúrà I am Túndé s mother. Ladi is a doctor. Tomorrow is market day. Mother is gold. However, one cannot say: * Dókítá jê Ládi * Öla jê æjà one would rather say Ládi jê dókítá Öla jê æjô æjà Negation kô When ni is negated, it becomes kô ni, as found in the examples below: Èmi ni bàbáa Kóyè. Èmi kô ni bàbáa Kóyè. Àwæn ni màmáà mi. Àwæn kô ni màmáà mi. Olú ni àbúrò Adé Olú kô ni àbúrò Adé I am Kóyè s father. I am not Kóyè s father. She is my mother. She is not my mother. Olú is Adé s younger sibling. Olú is not Adé s younger sibling.»é àwæn ni olùkôö r? Is s/he your teacher? Rárá, àwæn kô ni olùkôö mi. No, he is not my teacher. Regular pronouns cannot be used with ni as in the following examples: *Mo ni dókítà *Ó ni olùkö Similarly, kô cannot be used with regular pronouns as in the following examples: *Mo kô ni dókítà *Ó kô ni olùkö COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 116 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kìíní (Lesson 1) I«ê»í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní òdì. Respond to the following questions negatively. 1.»é bàbáà r ni olórí ìlú? 2.»é àwæn ni ëgbônæn Kíkê? 3.»é ìwæ ni dókítà? 4.»é êjæ àti eéjì ni êsànán? 5.»é èmi àti ìwæ ni ëyin? I«ê»í«e 2 Yí àwæn gbólóhùn yí sí òdì. Turn the following into negative. 1. Bàbáà mi jê olórí ìlú. 2. Àwæn ni ëgbônön mi. 3. Ó jê ælôpàá. 4. Èmi àti iwæ ni örê. 5. Mo jê agb jôrò. COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 117 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kìíní (Lesson 1) I«ê»í«e 3 Lo jê tàbí ni láti fi dí àwæn àlàfo wönyí. Use jê or ni to fill out the blank spaces below. 1. Màmáà mi nôösì. 2. Èmi mò ñ «i«ê ní ilé-ìwé. 3. Wôn öjögbôn ní ilé-ìwèé mi. 4.»é àwæn màmáà r? 5. Èmi æmæ bàbáatádè. 6. Ó mà«e o. Ó æmædé nií. I«ê»í«e 4 Yí àwæn gbólóhùn wönyí sí òdì. Turn the following sentences into negation. 1. Mo jê nôösì 2. A jê akêköô 3. O jê dókítà 4. jê öjögbôn 5. Ó jê olùkô 6. Wôn jê olórí ìlú COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 118 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kejì (Lesson 2) The interrogative ta ni implies who Ta ni örêë r? Ta ni bàbáà r? Lesson 2 - Ëkô Kejì: The interrogative Ta ni Ìsöröngbèsì (Dialogue) Ælá: Bàbáà mi, mo ní örê kan. Dad, I have a friend. Bàbá Ælá: Ìy n dára o. Ta ni örêë r? That s nice. Who is your friend? Ælá: Orúkæ rë ni Láñre. His name is Láñre. Bàbá Ælá: Ta ni bàbáa Láñre? Who is Láñre s father? Ælá: Öjögbôn Ö«úndáre ni bàbáa Láñre Professor Ö«úndáre is Láñre s father. Cultural Vignette: ÀPÔNLÉ Àpônlé jê ökan lára à«à àti i«é àwọn Yorùbá. Yorùbá máa õ pa á lówe pé: ni tí ó bá ju ni læ lè juni nù. Ìtumö èyí ni pé, ni tí ó bá ju ènìyàn læ ní ægbôn àti òye ju ènìyàn læ. Àwôn Yorùbá á tún máa wípé: Àìböwö fún àgbà ni kò jê kí ayé ó gún. Eléyìí túmö sí pé: ilé ayé ñ dàrú nítorí wí pé àwæn ènìyàn kò «e àpônlé tí ó y fún àwọn tí ó jù wôn læ. Bàbá àti ìyá ènìyàn nìkan kô ló y kí ènìyàn «e àpônlé fún. Ó «e pàtàkì fún gbogbo ènìyàn láti «e àpônlé fún ëgbôn, bí, ará àti ojúlùmö tó bá junì læ. Ènìyàn kò gbædö pe àgbàlagbà lórúkæ. Bùrödáa lágbájá tàbí àõtíi/sìsìtáa lágbájá ni ènìyàn gbædö pe ni tí ó bá junì læ. Ìdöbálë ni ækùnrin máa ñ kí ni tí ó bá ju ènìyàn læ. Àwæn obìnrin máa ñ kúnlë láti fi àpônlée wæn hàn. Ní önà mìíràn, ènìyàn kò gbædö lo ó fún ni tí ó bá dàgbà ju ènìyàn læ, kódà kó jê wí pé ödún kàn péré ni ni náà gbà lôwô ènìyàn. ni tí kò bá ní ëkô ilé ní ó máa ñ pe àgbàlagbà lórúkæ. Ara kô ilé ni bí a ti «e ñ kí àwæõ tí ó bá ju ènìyàn læ. COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 119 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô Kejì (Lesson 2) I«ê»í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Ta ni ó y kí ènìyàn «e àpônlé fún? 2. Kí ni àpônlé ní ilë Yorùbá? 3. Ta ni ó máa ñ pe àgbàlagbà lórúkæ? 4. Kí ni ìtumö òwe yìí: ni tí ó bá ju ni læ lè juni nù? 5. Kí ni àpônlé ní ìlúù r? COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 120 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) Lesson 3 - Ëkô K ta: bí ní ìdílé Mêta (Three Generations of a Family) COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 121 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Kí ni orúkæ ìdílée bàbá Àdùk? 2. Kí ni orúkæ bàbáa bàbá Àdùk? 3. Ta ni màmá Àdùkê? 4. Ta ni æmæ æmæ Æláníkëê? 5. Ta ni àwæn æmæ æmæ Æláníkëê? 6. Æmæ mélòó ni Æláníkëê ní? 7. Æmæ æmæ mélòó ni Æláníkëê ní? 8. Ta ni Babalælá? 9. Ta ni àbúròo Gbádébö? 10. Ta ni ëgbôn Àdùkê? COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 122 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 2 Parí àwæn örö wönyí. Complete the following sentences. Bí àp r : Babalælá ni ækæ Títílælá. Òun ni bàbáa Atinúkê àti Gbádébö. Òun sì ni ækæ æmæ Æláníkëê àti Adéníyì 1. Adéníyì ni 2. Gbádébö ni 3. Olútóókê ni 4. Bádé ni 5. Atinúkê ni I«ê»í«e 3 Sæ lóòótô ni tàbí lóòótô kô fún àwæn gbólóhùn wönyí. State whether the following sentences are true or false. Òótô ni Òótô kô 1. Àdùkê ni ækæ Ælá«ùpö. 2. Ælá«ùpö ni ìyàwó Àdùkê. 3. Atinúkê ni æmæ æmæ Æláníkëê. 4. Bádé ni bàbá Atinúkê. 5. Adéníyì ni bàbáa bàbáa Gbádébö. 6. Babalælá ni bàbáa Gbádébö. 7. Olútóókê ni ëgbônæn Títílælá. 8. Æláníkëê ni ìyàwó Adéníyì. 9. Ælá«ùpö ni æmææ Bádé. 10. Bádé àti Títí ni àwæn æmæ Adéníyì àti Æláníkëê. COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 123 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 4 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions. Bí àp r : Ækæ Títílælá ni? Babalælá 1. Bàbáa bàbá Àdùkê ni? 2. Òbí Àdùkê àti Ælá«ùpö ni? 3. Bàbáa Bádé ni? 4. Æmææ Bádé ni? 5. Æmææ Babalælá àti Títílælá ni? COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 124 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) Wá àwæn örö wönyí. Look for these words in the puzzle below. Pay attention to the tones! àpônlé à«à àgbàlagbà bùrödá ægbôn ìdöbálë wúrà ìdílé olórí ìdàgbàsókè à g b a l a d à b á d í l é à d ì l e l o b í «æ l a ó g l w í d á g b á s d à l e l a a d ú k í ó b à ó k ö í k o l æ w u r á l e a g í b æ a l a g ó t b à í é d á b ö á g á m b ì g i d ö b à d g à í j b n o á d d ö o d í p o k l b a ô l k í ö g l b ó d ô l b à b k n o g a b i t ù s a n í n g á b ó l o r á í n r á b l d ó b a a d ó s á l ö b ö r d é k i à ö k o r ó b ë l á d í l a r i a d á b í o d ó b i á g d í b b Ì d à g b à s ó k è í k e à COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 125 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) Cultural Vignette: bí ní ilë Yorùbá Ní ilë Yorùbá, mölêbí jê àkójæpö àpapö igun. Baálé ilé ni olórí igun köökan. Ètò bí jê nõkan tí ó «e pàtàkì fún àlàáfíà láàárín àwæn æmæ bí àti ìlú lápapö. Ìdí èyí ni wí pé, àlàáfíà láàárín mælêbí «e kókó fún ìdàgbàsókè ìlú. Yorùbá ní ìgbàgbô wí pé ìlé lè dàrú tí àlàáfíà kò bá sí láàárínin mælêbí. Gbogbo ènìyàn ni ó gbôdö jê mælêbí kan tàbí òmíràn. Nítorí èyí ni Yorùbá fi máa ñ sæ wí pé: A kìí wáyé ká má lêbí. Ìpàdée mælêbí máa ñ wáyé ní ösöösë tàbí ní o«oo«ù. Nígbà mìíràn, àwæn mælêbí máà ñ ní ìpàdé pàjáwìrì. Gbogbo mælêbí tún máa ñ kóra jæ láti «e ìgbéyàwó, ìsæmælórúkæ àti ìjádeòkù. Gbogbo bí ni ó ní olórí bí. Olórí bí jê ækùnrin tí ó dàgbà jùlæ nínúu mælêbí.»ùgbôn nígbà mìíràn olórí bí lè jê obìnrin tí ó dàgbà jùlæ nínúu mælêbí. Ara àwæn ojú«e olórí bí ni píparí aáwö láàárín àwæn mælêbí. Olórí bí tún máa ñ «ojú àwæn mælêbíi rë ní ìpàdé àdúgbò, ìpàdé agbolé, tàbí ìpàdé ìlú. Ó «e pàtàkì kí olórí bí rí i wí pé bí kò tú mô òun lórí. Ìdàgbàsókè bí ní í «e pëlú irú olórí bí tí wôn bá á ní. I«ê»í«e 6 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Kí ni pàtàkì mölêbí ní ilë Yorùbá? 2. Ta ni olórí bí ní ilë Yorùbá? 3. Kí ni i«ê olórí bí nínú bí àti ní ìlú? 4. Kí ni mælêbí jê fún ìdàgbàsókè ìlú? 5. Kí ni ìtumöæ mælêbí? COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 126 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 7 Túmö àwæn örö wönyí ni èdèe Yorùbá. Provide the meanings of the following words in Yorùbá Language. 1. olórí 2. Ìpàdé 3. gbôdö 4. ojú«e 5. baálé ilé Örö àdásæ (Monologue) Àbíkê ñ sörö nìpa bíi rë fún Arábìnrin Fáladé, olùkôæ rë. Àbíkê is talking about her family to Mrs. Fáladé, her teacher. bíì mi (My Family) bíì mi ni bí Adédìran À ñ gbé ní ìlú Ìbàdàn ní àdúgbò Ìyágànkú. Bàbá àti ìyáà mi bí æmæ mêrin. Àkôbí wæn ñ jê Adéolú. Æmæ ædún méjìlélôgbön ni wôn. Apòògùn sì ni wôn pëlú. Wôn ní ìyàwó. Orùkæ ìyàwóo wæn ni Gbémi. Wôn bí æmæ méjì, Doyin àti Yétúndé. Ækùnrin ni Doyin. Doyín jê æmæ ædún mêrin. Yétúndé sì jê æmæ ædún méjì. Æmæ kejì tí bàbáà àti màmáà mi bí ni Bímpé. Bímpé jê æmæ ægbön ædún. Dókítà ni wôn, «ùgbôn wôn kò ì tí ì fê ækæ. ni tí ó tëlé Bímpé ni Jídé. Æmæ ædún mêrìndínlôgbön ni wôn. Agb jôrò ni wôn. Wôn «ësë bí æmæ kan tí orúkæ rë ñ jê Rónkê. Rónkê jê æmæ o«ù mêta. Èmi ni àbígbëyìn nínú bíì mi. Orùkæö mi ni Àbíkê. Mo jê æmæ ædún méjìlélógún. Mo wà ní Yunifásítì ti ìlú Ìbàdàn. Mo ñ kô nípa ëkô ì«ègùn. COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 127 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 8 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Respond to the following questions. 1. Kí ni orúkæ ni tí ó ñ sörö? 2. Kí ni i«ê tí Bímpé ñ «e? 3. Ipò wo ni Adéolú wà nínú bí yìí? 4. Kí ni orúkæ àdúgbò àwæn Àbíkê? 5. Kí ni orúkæ ìyàwó Adéolú? 6. Ta ni wôn bí tëlé Bímpé? 7. Æmæ ædún mélòó ni Jídé? 8. Kí ni orúkæ àwæn æmæ Adéolú? 9. Kí ni orúkæ ilé-ìwé gíga Àbíkê? 10. Kí ni orúkæ bí yìí? COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 128 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 9 Parí àwæn örö wönyí. Complete the following based on the monologue. Bí àp r : Æmæ ædún méjìlélógún ni = Àbíkê 1. Apòògùn ni = 2. Ìyàwó Adéolú ni = 3. Doyin àti Yétúndé ni = 4. Æmæ kejìi bàbáà àti màmáà mi ni = 5. Æmæ ædún mêrin ni = 6. Æmæ ædún méjì ni = 7. Æmæ ægbön ædún ni = 8. Dókítà ni = 9. Ó ñ kô nípa ëkô ì«ègùn = 10. Æmæ æ«ù mêta ni = 11. Àbígbëyìn ni = 12. Agb jêrò ni = 13. Æmæ ædún mêrìndínlôgbön ni = 14. Æmæ Yunifásítì ni = 15. Ó ñ sörö nìpa bíi rë = Örö àdásæ (Monologue) bí Akínwálé Orúkæ mi ni Lælá. Orúkæ bàbáà mi ni Fêmi. Orúkæ màmáà mi ni Æláníkëê. Mo ní abúrò mêta. Orúkæ wæn ni Jídé, Báyö àti Bùnmi. Jídé àti Báyö ni àwæn abúrò mi ækùnrin, Bùnmi sì ni àbúrò mi obìnrín. Jídé ni æmæ kejì. Báyö ni æmæ k ta. Bunmi ni àbúrò mi àbígbëyìn. À ñ gbé ní ìlú Èkó. Mo fêrànan gbogbo àwæn bíì mi gan-an ni. COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 129 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) bí Akínwálé Baba ati Mama Femi Olanikee Lola Jide Bayo Bunmi I«ê»í«e 10 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences. 1. Kí ni orúkæ bíi Lælá? 2. Kí ni orúkææ bàbáa Jídé? 3. Ta ni Báyö? 4. Kí ni orúkæ àwæn àbúròo Lælá? 5. Ta ni Æláníkëê? 6. Kí ni orúkæ ëgbônæn Lælá? 7. Ta ni Bùnmi? 8. Æmæ mélòó ni ó wà nínú bí Akínwálé? COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 130 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 11 Mú èyí tí ó bá tönà nínú àwæn ìdáhùn wönyí. Circle the correct answer. 1. Orúkæ bàbáa Lælá ni? a. Gbénga b. Fêmi c. Báyö d.»eun 2. Kí ni orúkæ àbúròo Bàyô? a. Lælá b. Bùnmi c. Kêmi d. Jídé 3. Æmæ mélòó ni Æláníkëê bí? a. Æmæ mêta b. Æmæ márùnún c. Æmæ kan d. Æmæ mêrin 4. Ëgbôn mélòó ni Bùnmi ní? a. Méjì b. Mêta c. Mêfà d. Mêrin 5. Ìlú wo ni bí Akínwálé ñ gbé? a. Ìbàdàn b. Abêòkúta c. Èkó d. Ilé-Ifë COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 131 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 12 Túmö àwæn örö wönyí ni èdèe Yorùbá. Provide the meanings of the following words in Yorùbá language. 1. My brother-in-law 2. Her mother-in-law 3. His niece 4. Your nephew 5. My first cousin 6. Our uncle 7. Your aunt 8. My grandfather 9. Their great grandfather 10. Her grandmother I«ê»í«e 13 So àwæn tí ó bara mu ni öwô A àti öwô B papö. Match the words in column A with those in column B. A B bí Bàbá Màmá Bàbáa bàbá Màmáa màmá Ëgbôn Àbúrò Younger sibling Older sibling Grandmother Grandfather Mother Father Family COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 132 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 14 So àwæn tí ó bara mu ni öwô A àti öwô B papö. Match the words in column A with those in column B. A B Ìkúnlë Ìdöbálë Àpônlé À«à Agbolé Respect Culture Compound Kneeling down Prostration I«ê»í«e 15 Ya àwòrán bíì r. Tí o bá «e é «e, ya àwòrán yìí títí dé ìran k ta. Draw a picture of your family, if possible a three- generation family tree. 1. Generation 2. Generation 3. Generation COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 133 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K ta (Lesson 3) I«ê»í«e 16 Mú fôtò bíì r wá sí kíláàsì. Fi fôtò bíì r han örêë r, jê kí örêë r gbìyànjú bóyá ó lè sæ nípa àwæn bíì r fún. Bring a picture of your family to class. Show it to your partner in class, and let your partner guess who the members of your family are. I«ê»í«e 17 Ní méjì méjì. (In pairs) Nínúu kíláàsì, láláìsí fôtò, «e àpèjúwe bíì r fún örêë r, kí örêë r náà sì «e àpèjúwe bíi rë fún ìwæ náà. kæ ohun tí sæ fún ara yín sílë. In pairs, without pictures, let each student describe his or her family to his or her partner. Each of you should write down what the other person said. COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 134 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K rin (Lesson 4) Lesson 4 - Ëkô K rin: Describing people Àbúròò mi ækùnrin lágbára Örêë mi sanra Mo kúrú Tádé ga My younger brother is strong My friend is fat I am short Tádé is tall Ëgbônön mi tínínrín Bàbáà mi kúrú Örêë mi tóbi Kò kúrú kò ga My older sibling is skinny My father is short My friend is big S/he is neither tall nor short Ènìyàn dúdú Ènìyàn pupa Ènìyàn funfun a black person a light-skinned person a white person Abíælá nìyí. Ó sanra. Kò ga. Ò«ì«ê ni. Sëìndè nìyí. Ó tínínrín. Ó ga. Ó yöl. COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 135 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K rin (Lesson 4) Kúnlé nìyí. Ó tóbi. Ó lágbára. Akínkanjú ènìyàn ni. Títí nìyí. Kò kúrú. Kò ga. Gerunds are formed from adjectival verbs. Some examples of adjectival verbs include ga (tall), sanra (fat) and tóbi (big). ga gíga sanra sísanra tóbi títóbi However, some adjectival verbs do not follow the above structure. Some examples include: kéré kékeré small kúrú kúkúrú short burú búburú wicked, mean Gerunds can be used to describe people. They follow their nouns. For example: màmáà mi jê ènìyàn gíga my mother is a tall person OR ènìyàn sísanra ni bàbáà mi my father is a fat person COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 136 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K rin (Lesson 4) The prefixes oní-, al-, æl-, l- (one who is ) can be added to the noun to describe people. For example: ægbôn ælôgbôn àánú aláàánú ìwàpëlê oníwàpëlê Example: màmáà mi jê ælôgbôn OR màmáà mi jê ælôgbôn ènìyàn OR ælôgbôn ènìyàn ni màmáà mi Olú ñ «e àpèjúwe bíi rë nínúu kíláàsì. Olú is describing his family in the classroom. Örö àdásæ (Monologue) Bàbáà mi tínínrín, wôn sì dúdú. Màmáà mi sanra, wôn sì pupa. Wôn lêwà. Kì í «e pé bàbáà mi búrêwà o! Wôn jê ælôgbôn, aláàánú àti onírëlë. Wôn sì tún jê ènìyàn gíga. Màmáà mi jê oníwàpëlê. Wæn kì í «e onígbéraga. Wæn kò ga bíi bàbáà mi. Wæn kò sì kúrú púpö. Wôn jê ènìyàn rere. Wôn sì jê æmælúwàbí ènìyàn. I«ê»í«e 1 Sæ lóòótô ni tàbí lóòótô kô fún àwæn gbólóhùn wönyí. State whether the following sentences are true or false. Òótô ni Òótô kô 1. Bàbá Olú sanra. 2. Màmá Olú ga. 3. Bàbá Olú jê oníwàpëlê. 4. Bàbá Olú kò búrêwà. 5. Màmá Olú kò gbéraga. COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 137 CC 2012 The University of Texas at Austin

Orí Karùnún (Chapter 5) Ëkô K rin (Lesson 4) I«ê»í«e 2»e àpèjúwe àwæn ènìyàn wönyí. Describe the following people. Bí àp r : Britney Spears = Ó kúrú, ó kéré, kò gbéraga. 1. George H. W. Bush = 2. Miley Cyrus = 3. 50 Cent = 4. Barack Obama = 5. Michael Jackson = 6. Michael Phelps = 7. Bill Clinton = 8. Hillary Clinton = 9. Carrie Underwood = 10. Michelle Obama = 11. Kanye West = 12. Oprah Winfrey = 13. Will Smith = 14. Paula Abdul = 15. Simon Cowell = 16. Christina Aguilera = 17. Angelina Jolie = 18. Brad Pitt = 19. Jennifer Aniston = 20. Nelson Mandela = 21. Dolly Parton = 22. Percy Sledge = 23. Beyoncé Knowles = 24. King Sunny Ade = 25. Fela Anikulapo Kuti = 26. Jennifer Aniston = 27. Denzel Washington = 28. Dalai Lama = 29. Muhammed Ali = 30. Martin Luther King Jr. = COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 138 CC 2012 The University of Texas at Austin